الكوثر
Al-Kawthar
Translation: Yoruba - Abu Rahima Mikhail Aikweiny · Open the surah
بِسۡمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ
إِنَّآ أَعۡطَيۡنَٰكَ ٱلۡكَوۡثَرَ
Open ayah 108:1Dájúdájú Àwa fún ọ ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ oore.
فَصَلِّ لِرَبِّكَ وَٱنۡحَرۡ
Open ayah 108:2Nítorí náà, kírun fún Olúwa rẹ, kí o sì gúnran (fún Un).
إِنَّ شَانِئَكَ هُوَ ٱلۡأَبۡتَرُ
Open ayah 108:3Dájúdájú, ẹni tó ń bínú rẹ, òun ni kò níí lẹ́yìn.